
Ǹjẹ́ Nàìjíríà dá àjọṣe lórí àwọn àlùmọ́ọ́nì láàárín òhun àti Amẹ́ríkà dúró nítorí visa?
Ẹni kan tí ó ń lo Facebook, ohun ìgbàlódé íbaraẹnisọrẹ lórí ayélujára ti sọ pé orílẹ̀ èdè Nàìjíríà hùwà sí orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, tí ó mú àdínkù bá bí àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣe lè wọlé sí Amẹ́ríkà, gẹ́gẹ́bí Amẹ́ríkà se se sí Nàìjíríà nípa dídá àjọṣe lórí àwọn …